Yoruba Hymn APA 371 - Jesu mimo, Ore airi

Yoruba Hymn APA 371 - Jesu mimo, Ore airi

Yoruba Hymn  APA 371 - Jesu mimo, Ore airi

APA 371

 1. Jesu mimo, Ore airi,

 Oluranlowo alaini,

 N’nu ayida aiye, ko mi,

 K’ emi le romo O.


2. Ki nsa n’ idapo mimo yi,

 Gba ohun t’O fen go kun bi?

 B’ okan mi, b’eka ajara,

 Ba sa le romo O.


3. Are ti m’okan mi pipo,

 Sugbon o wa r’ibi ‘simi;

 Ibukun si de s’okan mi,

 T’ori t’o romo O.


4. B’aiye d’ofo mo mi l’oju,

 B’a gba ore at’ ara lo,

 Ni suru ati laibohun

 L’emi o romo O.


5. Gbat’ o k’emi nikansoso

 L’arin idamu aiye yi,

 Mo gb’Ohun ife jeje na

 Wipe, “Sa romo Mi.”


6. B’are ba fem u igbagbo,

 T’ ireti ba si fe saki,

 Ko si ewu fun okan na

 Ti o ba romo O.


7. Ko beru irumi aiye,

 Niotir ‘Wo wa nitosi;

 Ki o si gbon b’iku ba de,

 Tori o romo O.


8. Ire sa ni l’ohun gboggbo,

 Wo agbara at’ asa mi;

 Olugbala, k y’o si nkan

 Bi mba ti romo O. Amin.Yoruba Hymn  APA 371 - Jesu mimo, Ore airi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 371- Jesu mimo, Ore airi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post