Yoruba Hymn APA 370 - Emi ‘ba le f’ iwa pele

Yoruba Hymn APA 370 - Emi ‘ba le f’ iwa pele

Yoruba Hymn  APA 370 - Emi ‘ba le f’ iwa pele

APA 370

 1. Emi ‘ba le f’ iwa pele

 Ba Olorun mi rin;

 Ki mni imole it nto mi

 Sodo Odagunta!


2. Ibukun ti mo ni ha da,

 ‘Gba mo ko mo Jesu?

 Itura okan na ha da,

 T’ oro Kristi fun mi?


3. Alafia mi nigbana,

 ‘Ranti re ti dun to!

 Sugbon nwon ti b’afo sile,

 Ti aiye ko le di.


4. Pada, Emi Mimo, pada,

 Ojise itunu:

 Mo ko ese t’o bi O n’nu,

 T’o le O lokan mi.


5. Osa ti mo fe rekoja

 Ohun t’ o wu ko je,

 Ba mi yo kuro lokan mi;

 Ki nle sin ‘Wo nikan.


6. Bayi ni ngo b’ OIorun rin,

 Ara o ro mi wo!

 ‘Mole orun y’o ma to mi

 Sodo Odaguntan. Amin.
Yoruba Hymn  APA 370 - Emi ‘ba le f’ iwa pele

This is Yoruba Anglican hymns, APA 370- Emi ‘ba le f’ iwa pele  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post