Yoruba Hymn APA 373 - Didan l’ opagun wa, o ntoka s’ orun

Yoruba Hymn APA 373 - Didan l’ opagun wa, o ntoka s’ orun

Yoruba Hymn  APA 373 - Didan l’ opagun wa, o ntoka s’ orun

APA 373

 1. Didan l’ opagun wa, o ntoka s’ orun,

 O nfonahan ogun, s’ ile won orun!

 Lar’naginju l’a nrin, l’ ayo l’ a ngbadura,

 Pel’ okan isokan l’ a ’m’ on’ orun pon.

 Didan l’ opagun wa, O ntoka s’ orun,

 O nfonahan ogun, s’ ile won orun.


2. Jesu Oluwa wa, l’ ese Re owo,

 Pelu okan ayo l’ omo Re pade:

 A ti fi O sile, a si ti sako.

 To wa Olugbala si ona toro.

 Didan l’ opagun wa, &c.


3. To wa l’ ojo gbogbo, l’ ona t’ awa nto,

 Mu wan so s’ isegun l’ or iota wa;

 K’ Angel Re s’ asa wa gb’ oju orun su;

 Dariji, si gba wa lakoko iku.

 Didan l’ opagun wa, &c.


4. K’ a le pelu awon Angeli loke,

 Lati jumo ma yin n’ite ife Re:

 ’Gbat’ ajo wa ba pin, isimi y’o de,

 At’ alafia, at’ orin ailopin.

 Didan l’ opagun wa, &c. Amin.
Yoruba Hymn  APA 373 - Didan l’ opagun wa, o ntoka s’ orun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 373- Didan l’ opagun wa, o ntoka s’ orun  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post