Yoruba Hymn APA 390 - Mo f’ara Mi fun o

Yoruba Hymn APA 390 - Mo f’ara Mi fun o

Yoruba Hymn  APA 390 - Mo f’ara Mi fun o

APA 390

 1. Mo f’ara Mi fun o,

 Mo ku nitori re,

 Ki nle ra o pada,

 K’ o le jinde nn’ oku;

 Mo f’ara mi funn o,

 Kini ‘wo se fun Mi?


2. Mo f’ ojo aiye Mi

 Se wahala fun o;

 Ki iwo ba le mo

 Adun aiyeraiye;

 Mo lo opo ‘dun fun o,

 O lo kan fun mi bi?


3. Ile ti Baba Mi,

 At’ ite ogo Mi;

 Mo fi sile w’ aiye;

 Mo d’ alalrinkiri:

 Mo f’ile tori re,

 Ki l’o f’ile fun Mi?


4. Mo jiya po fun o,

 Ti enu ko le so;

 Mo jijakadi nla,

 ‘Tori igbala re;

 Mo jiya po fun o,

 O le jiya fun Mi?


5. Mo mu igbala nla,

 Lati’ ile Baba Mi

 Wa, lati fi fun o;

 Ati idariji;

 Mo m’ ebun wa fun o,

 Kil ‘o mu wa fun Mi.


6. Fi ara re fun Mi,

 Fi aiye re sin Mi;

 Diju si nkan t’ aiye,

 Si wo ohun t’ orun;

 Mo f’ara Mi fun o,

 Si f’ ara re fun Mi. Amin.



Yoruba Hymn  APA 390 - Mo f’ara Mi fun o

This is Yoruba Anglican hymns, APA 390- Mo f’ara Mi fun o . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post