Yoruba Hymn APA 391 - Gb’ agbelebu re, ni Krist wi

Yoruba Hymn APA 391 - Gb’ agbelebu re, ni Krist wi

Yoruba Hymn  APA 391 - Gb’ agbelebu re, ni Krist wi

APA 391

 1. Gb’ agbelebu re, ni Krist wi,

 B’o ba fe s’ omo-ehin Mi;

 Se ‘ra re, ko aiye sile,

 Si ma f’ irle tele Mi.


2. Gb’ agbelebu re, ma je ki

 Iwuwo re fo o laiya:

 Ipa Mi y’o gb’ emi re ro,

 Y’o m’ okan at’ apa re le.


3. Gb’ agbelebu re, ma tiju,

 Ma je k’okan were re ko;

 Oluwa ru agbelebu,

 Lati gba o lowo iku.


4. Gb’ agbelebu re, n’ ipa Re

 Rora ma la ewu ja lo;

 Y’o mu o de ile ayo;

 Y’o mu o segun iboji.


5. Gb’ agbelebu re, ma tele,

 Mase gbe sile tit’ iku;

 Enit’ o ru agbelebu,

 L’o le reti lati d’ ade.


6. ‘Wo Olorun Metalokan,

 L’a o ma yin titi aiye;

 Fun wa, k’a le ri n’ ile wa,

 Ayo orun ti ko lopin. Amin.Yoruba Hymn  APA 391 - Gb’ agbelebu re, ni Krist wi,

This is Yoruba Anglican hymns, APA 391- Gb’ agbelebu re, ni Krist wi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post