Yoruba Hymn APA 392 - Tan ‘mole Re si wa

Yoruba Hymn APA 392 - Tan ‘mole Re si wa

Yoruba Hymn  APA 392 - Tan ‘mole Re si wa

APA 392

 1. Tan ‘mole Re si wa

 Loni yi Oluwa;

 Fi ara Re han wa

 N’nu oro mimo Re;

 Jo m’okan wa gbona,

 K’ a ma wo oju Re,

 K’ awon ‘mode le ko

 Iyanu ore Re.


2. Mi si wa Oluwa,

 Ina Emi Mimo,

 K’ a le fi okan kan

 Gbe oruko Re ga;

 Jo fi eti igbo,

 At’ okan ironu,

 Fun awon ti a nko,

 L’ ohun nla t’ O ti se.


3. Ba ni so, Oluwa,

 Ohun to ye k’ a so,

 Gege bi oro Re,

 Ni ki eko wa je;

 K’ awon agutan Re,

 Le ma mo ohun Re,

 Ibit’ O nto won si,

 Ki nwon si le ma yo.


4. Gbe ‘nu wa, Oluwa,

 K’ife Re je tiwa,

 Iwo nikan lao fi

 Ipa wa gbogbo sin;

 K’ iwa wa je eko,

 Fun awon omo Re,

 K’o si ma kede Re,

 Ninu gbogbo okan. Amin.Yoruba Hymn  APA 392 - Tan ‘mole Re si wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 392- Tan ‘mole Re si wa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post