Yoruba Hymn APA 396 - Funrugbin lowuro

Yoruba Hymn APA 396 - Funrugbin lowuro

Yoruba Hymn  APA 396 - Funrugbin lowuro

APA 396

 1. Funrugbin lowuro,

 Ma simi tit’ ale;

 F’ eru on ’yemeji sile,

 Ma fun sibi-gbogbo.


2. ’Wo ko mo ’yi ti nhu,

 T’ oro tabi t’ ale:

 Ore-ofe yio pa mo,

 ’Bit’ o wu k’o bo si.


3. Yio si hu jade

 L’ ewa tutu yoyo,

 Beni y’o si dagba soke,

 Y’o s’ eso nikehin.


4. ’Wo k’ y’o sise lasan!

 Ojo, iri, orun,

 Yio jumo sise po

 Fun ikore orun.


5. Nje nikehin ojo,

 Nigbat’ opin ba de,

 Awon Angel’ y’o si wa ko

 Ikore lo sile. Amin.Yoruba Hymn  APA 396 - Funrugbin lowuro

This is Yoruba Anglican hymns, APA 396-Funrugbin lowuro . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post