Yoruba Hymn APA 397 - Olorun ogbon at’ ore

Yoruba Hymn APA 397 - Olorun ogbon at’ ore

Yoruba Hymn  APA 397 - Olorun ogbon at’ ore

APA 397

 1. Olorun ogbon at’ ore,

 Tan ’mole at’ oto,

 Lati f’ ona toro han wa,

 Lati to ’sise wa.


2. Lati to ’pa wa n’nu ewu,

 Li arin apata;

 Lati ma rin lo larin won,

 K’a m’ oko wa gunle.


3. B’ o’r ofe Re tin mu wa ye,

 K’ a ko won b’ eko Re,

 A wa lati to omo wa

 Ni gbogbo ona Re.


4. Li akoko, pa ife won,

 On ’gberaga won run;

 K’a fi ona mimo han won,

 Si Olugbala won.


5. A fe woke nigbakugba,

 K’ a to apere Re;

 K’a ru ’beru, on ’reti won,

 K’a tun ero won se.


6. A fe ro won lati gbagbo,

 Ki nwon f’ itara han;

 Ki a mase lo ikanra,

 ’Gbat’ a ba le lo’ fe.


7. Eyi l’a f’ igbagbo bere,

 Ogbon t’o t’oke wa;

 K’a f’ eru omo s’ aiya won,

 Pelu ife mimo.


8. K’a so ’fe won ti nte s’ibi,

 Kuro l’ ona ewu;

 K’a fi pele te okan won,

 K’a fa won t’ Olorun. Amin.Yoruba Hymn  APA 397 - Olorun ogbon at’ ore

This is Yoruba Anglican hymns, APA 397- Olorun ogbon at’ ore. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post