Yoruba Hymn APA 401 - Aye si mbe!” ile Odagutan

Yoruba Hymn APA 401 - Aye si mbe!” ile Odagutan

 Yoruba Hymn  APA 401 - Aye si mbe!” ile Odagutan

APA 401

1. “Aye si mbe!” ile Odagutan,

 Ewa ogo re npe o pe, “Ma bo.”

 Wole, wole, wole nisisiyi.


2. Ojo lo tan, orun si fere wo,

 Okunkun de tan, ’mole nkoja lo;

 Wole, wole, wole nisisiyi.


3. Ile iyawo na kun fun ase!

 Wole, wole, to Oko-’yawo lo:

 Wole, wole, wole nisisiyi.


4. “Aye si mbe!” ilekun si sile,

 Ilekun ife; iwo kop e ju.

 Wole, wole, wole nisisiyi.


5. wole! wole! tire ni ase na,

 Wa gb’ ebun ’fe aiyeraiye lofe!

 Wole, wole, wole nisisiyi.


6. Kiki ayo l’o wa nibe; wole!

 Awon angeli npe o fun ade.

 Wole, wole, wole nisisiyi.


7. Lohun rara n’ ipe ife na ndun!

 Wa, ma jafara, wole ase na.

 Wole, wole, wole nisisiyi.


8. O nkun! o nkun! ile ayo na nkun!

 Yara! mase pe, ko kun ju fun o.

 Wole, wole, wole nisisiyi.


9. K’ ile to su, ilekun na le ti!

 ’Gbana, o k’ abamo! “Ose! Ose!”

 Ose! Ose! ko s’ aye mo, ose! Amin.Yoruba Hymn  APA 401 - Aye si mbe!” ile Odagutan

This is Yoruba Anglican hymns, APA 401- Aye si mbe!” ile Odagutan . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post