Yoruba Hymn APA 405 - Tire l’ola Baba

Yoruba Hymn APA 405 - Tire l’ola Baba

Yoruba Hymn  APA 405 - Tire l’ola Baba

APA 405

 1. Tire l’ola Baba,

 O wa n’ ikawo Re;

 B’ ojum’ ola si mo ba ni,

 Nipa ase Re ni.


2. Akoko y info lo,

 O ngbe emi wa lo;

 Oluwa, mu ’ranse Re gbon,

 Kin won le wa fun O.


3. Akoko t’ o nlo yi,

 L’ aiyeraiye ro mo,

 Fi agbara Re Oluwa,

 Ji agba at’ ewe.


4. On kan l’a ba ma du,

 T’ a ba ma lepa re;

 Pe k’ igba ’bewo wa ma lo,

 Laitun pada wa mo.


5. Je k’a sa to Jesu,

 K’ a si sure tete;

 K’ emi wa ma ba ku, k’ o ri

 S’ okun biribiri. Amin.Yoruba Hymn  APA 405 - Tire l’ola Baba

This is Yoruba Anglican hymns, APA 405- Tire l’ola Baba . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post