Yoruba Hymn APA 414 - F’ awon enia Re

Yoruba Hymn APA 414 - F’ awon enia Re

Yoruba Hymn  APA 414 - F’ awon enia Re

APA 414

 1. F’ awon enia Re,

 T’ o ti f’ aiye sile;

 Awon t’ o mo O, t’ o sin O,

 Gba orin iyin wa.


2. F’ awon enia Re,

 Gba ohun ope wa;

 Awon t’ o fi O s’ esan won,

 Nwon ku n’ igbagbo Re.


3. Ni gbogbo aiye won,

 ’Wo ni nwon nwo l’oju:

 Emi Mimo Re l’o nko won,

 Lati s’ ohun gbogbo.


4. Fun eyi, Oluwa,

 A nyin oruko Re;

 Je k’ a ma tele iwa won,

 Ki a le ku bi won. Amin.



Yoruba Hymn  APA 414 - F’ awon enia Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 414-  F’ awon enia Re . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post