Yoruba Hymn APA 444 - K’ On to de, - je k’oro yi

Yoruba Hymn APA 444 - K’ On to de, - je k’oro yi

 Yoruba Hymn  APA 444 - K’ On to de, - je k’oro yi

APA 444

1. ‘K’ On to de, - je k’oro yi

 Ma dun titi l’eti re;

 Je ki sa die t’o ku

 Han gbangba daju fun o;

 Ronu b’orun on ile

 Ti d’ ehin gbat’ O ba de.’


2. Gbat’ awon ti a feran

 Bo si ‘simi won l’oke,

 T’o jo pe aiye wa pin,

 Ti adun re si koro;

 E dakun, e ma b’ohun,

 Kiki ‘k’ On to de’ sa ni.


3. Ibanuje yi wa ka;

 A ha fe k’o dinku bi?

 Gbogbo of aiye yi,

 Iku, ofo on ‘boji

 Nso jeje pe, ‘K’ On t’o de.


4. Wo tabil’ ife t’a te,

 Mu waini, si j’akara;

 ‘Ranti didun, - k’ Oluwa

 To pew a s’ onje orun;

 ‘Mi lat’ aiye, ‘mi l’orun,

 Nwon pinya tit’ On fi de.’ Amin.Yoruba Hymn  APA 444 - K’ On to de, - je k’oro yi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 444- K’ On to de, - je k’oro yi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post