Yoruba Hymn APA 445 - Jesu, Iwo l’ a gbohun si
APA 445
1. Jesu, Iwo l’ a gbohun si,
Mi Emi Mimo Re
Si awon enia wonyi;
Baptis won s’ iku Re.
2. K’ o fi agbara Re fun won,
Fun won l’ okan titun!
Ko ’oruko Re si aiya won,
Fie mi Re kun won.
3. Je ki nwon ja bi ajagun
Labe opagun Re,
Mu won f’ otito d’ amure,
Ki nwon rin l’ ona Re.
4. Oluwa, gbin wa s’ iku Re,
K’ a jogun iye Re;
Laiye k’ a ru agbelebu,
K’ a ni ade orun. Amin.
Yoruba Hymn APA 445 - Jesu, Iwo l’ a gbohun si
This is Yoruba Anglican hymns, APA 445- Jesu, Iwo l’ a gbohun si. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals