Yoruba Hymn APA 455 - Baba, Apat’ agbara wa

Yoruba Hymn APA 455 - Baba, Apat’ agbara wa

Yoruba Hymn  APA 455 - Baba, Apat’ agbara wa

APA 455

 1. Baba, Apat’ agbara wa,

 Ileri eniti ki ’ye,

 Sinu agbo enia Re,

 Jo, gba omo yi titi lai.


2. A ti f’omi yi sami fun,

 Li Oruko Metalokan;

 A si ntoro ipo kan fun,

 Larin awon omo Tire.


3. A sa l’ami agbelebu,

 Apere iya ti O je;

 Krist, k’ ileri re owuro

 Je ’jewo ojo aiye re.


4. Fifunni, k’iku on iye,

 Ma ya omo Re lodo Re;

 K’ on je om’-ogun Re toto,

 Om’odo Re, Tire lailai. Amin.Yoruba Hymn  APA 455 - Baba, Apat’ agbara wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 455- Baba, Apat’ agbara wa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post