Yoruba Hymn APA 456 - Jesu, Baba omode

Yoruba Hymn APA 456 - Jesu, Baba omode

Yoruba Hymn  APA 456 - Jesu, Baba omode

APA 456

 1. Jesu, Baba omode,

 Ase Re ni awa nse;

 A m’omo yi wa ’do Re,

 Ki iwo so di Tire.


2. Ninu ese ni a bi,

 We kuro nin’ ese re;

 Eje Re ni a fi ra,

 K’o pin ninu Ebun Re. Amin.



Yoruba Hymn  APA 456 - Jesu, Baba omode

This is Yoruba Anglican hymns, APA 456- Jesu, Baba omode. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post