Yoruba Hymn APA 458 - Jesu, ’Wo onirele

Yoruba Hymn APA 458 - Jesu, ’Wo onirele

Yoruba Hymn  APA 458 - Jesu, ’Wo onirele

APA 458

 1. Jesu, ’Wo onirele,

 Wo mi, emi omode;

 Kanu fun aimokan mi,

 Si je k’ emi wado Re.


2. Mo fe lati wado Re,

 Oluwa mi, mase ko;

 Oluwa, fun mi n’ ipo,

 Ninu ’joba ore Re.


3. Odagutan Olorun,

 ’Wo ni k’o j’ apere mi;

 Iwo tutu, ’Wo tenu;

 O si ti s’ omode ri.


4. Jesu, Ore omode,

 Ni owo Re ni mo wa;

 Se mi gege b’ O ti ri,

 Si ma gbe ’nu mi titi. Amin .Yoruba Hymn  APA 458 - Jesu, ’Wo onirele

This is Yoruba Anglican hymns, APA 458- Jesu, ’Wo onirele. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post