Yoruba Hymn APA 461 - Opo ikan omi
APA 461
1. Opo ikan omi,
Yanrin kekeke;
Wonyi l’ o d’ okun nla,
At’ ile aiye.
2. Iseju wa kokan,
Ti a ko kasi,
L’ o nd’ odun aimoye
Ti ainipekun.
3. Iwa ore die,
Oro ’fe die,
L’ o ns’ aiye di Eden,
Bi oke orun.
4. Isise kekeke
L’ o nmokan sina,
Kuro l’ ona rere,
Si ipa ese.
5. Ise anu die
T’a se l’omode,
Di ’bukun f’orile
T’o jina rere.
6. Awon ewe l’ ogo
Ngberin Angeli;
Se wa ye Oluwa
F’ egbe mimo won. Amin.
Yoruba Hymn APA 461 - Opo ikan omi
This is Yoruba Anglican hymns, APA 461- Opo ikan omi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals