Yoruba Hymn APA 460 - Bi osun gbege eti ’do

Yoruba Hymn APA 460 - Bi osun gbege eti ’do

 Yoruba Hymn  APA 460 - Bi osun gbege eti ’do

APA 460 

1. Bi osun gbege eti ’do,

 Tutu mini-mini;

 B’ igbo dudu eti omi,

 B’ itanna ipado.


2. Be l’ omo na yio dagba,

 Ti nrin l’ona rere,

 T’okan re nfa si Olorun,

 Lat’ igba ewe re.


3. Ewe tutu l’eba odo,

 B’o pe, a re danu;

 Be n’ itanna ipa omi

 Si nre l’akoko re.


4. Ibukun ni fun omo na,

 Ti nrin l’ona Baba;

 Oba ti ki pa ipo da,

 Eni mimo lailai.


5. Oluwa, ’Wo l’a gbekele,

 Fun wa l’ore-ofe;

 L’ ewe, l’agba, ati n’iku,

 Pa wa mo b’omo Re. Amin.Yoruba Hymn  APA 460 - Bi osun gbege eti ’do

This is Yoruba Anglican hymns, APA 460- Bi osun gbege eti ’do . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post