Yoruba Hymn APA 476 - Awon kekeke wo l’ eyi

Yoruba Hymn APA 476 - Awon kekeke wo l’ eyi

Yoruba Hymn  APA 476  - Awon kekeke wo l’ eyi

APA 476

 1. Awon kekeke wo l’ eyi

 T’ nwon tete l’ ajo aiye ja,

 Ti nwon si de ’bugbe ogo,

 Eyiti nwon ti nf’ oju si?


2. “Emi t’ oke Grinlandi wa.”

 “Emi, lati ile India.”

 “Emi t’ ile Afrika wa.”

 “Emi, lat’ Erekusu ni.”


3. Irin ajo wa ti koja,

 Ekun ati irora tan;

 A jumo pade nikehin,

 Li enu ibode orun.


4. A nreti lati gbo pe, “Wa,”

 Asegun ese on iku:

 Gb’ ori nyin soke, ilekun,

 K’ awon ero ewe wole. Amin.Yoruba Hymn  APA 476  - Awon kekeke wo l’ eyi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 476- Awon kekeke wo l’ eyi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post