Yoruba Hymn APA 477 - Odagutan, ’Wo ti re

Yoruba Hymn APA 477 - Odagutan, ’Wo ti re

Yoruba Hymn  APA 477 - Odagutan, ’Wo ti re

APA 477

 1. Odagutan, ’Wo ti re

 Omo Re kekere l’ ekun:

 Wo b’ o ti dubule je

 Layo ninu iboji Re:

 Ko s’ ami irora mo,

 T’ o nyo okan Re lenu.


2. ’Wo ko mu pe titi mo

 L’ aiye ekun on osi yi;

 Iwo si f’ ayo gba a

 Si ile orun mimo ni;

 O woso ala mimo,

 O mba O gbe n’ imole.


3. L’ aipetiti, Oluwa

 Mu wa de ’bit’ omo yi lo;

 Mu wa r’ ile ayo na,

 T’ o nf’ onje orun bo won:

 B’ O ti gb’ ayo wa lo yi,

 ’Gbana ao tun jere re. Amin .Yoruba Hymn  APA 477 - Odagutan, ’Wo ti re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 477- Odagutan, ’Wo ti re . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post