Yoruba Hymn APA 484 - Wa, ba wa jeun, Oluwa

Yoruba Hymn APA 484 - Wa, ba wa jeun, Oluwa

Yoruba Hymn  APA 484 - Wa, ba wa jeun, Oluwa

APA 484

 I. Wa, ba wa jeun, Oluwa,

Je k’ a ma yin oruko Re;

Wa busi onje wa; si je

K’ a le ba O jeun l’ orun. Amin.


II. A f’ ope fun O, Oluwa,

Fun onje wa, at’ ebun mi;

Fi onje orun b’ okan wa,

Onje iye lat’ oke wa. Amin.Yoruba Hymn  APA 484 - Wa, ba wa jeun, Oluwa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 484- Wa, ba wa jeun, Oluwa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post