Yoruba Hymn APA 492 - Olusagutan mi

Yoruba Hymn APA 492 - Olusagutan mi

Yoruba Hymn  APA 492 - Olusagutan mi

APA 492

 1. Olusagutan mi,

 Ma bo mi titi;

 Olusagutan mi,

 Ma to ese mi.


2. Di mi mu, si to mi,

 Ni ona hiha;

 B’ O ba wa lodo mi,

 Emi ko sina.


3. Sin mi s’ ona orun,

 Ni ojojumo;

 Ma busi ’gbagbo mi,

 Si mu mi fe O.


4. K’ ayo tabi ekun,

 Ti odo Re wa;

 K’ iye ainipekun,

 Le je ayo mi.


5. Ma pese okan mi,

 Ni ojojumo;

 Si je k’ Angeli Re,

 Sin mi lo ile. Amin.



Yoruba Hymn  APA 492 - Olusagutan mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 492- Gba Jesu wo tempili lo . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post