Yoruba Hymn APA 500 - Ojo nla l’ ojo ti mo yan

Yoruba Hymn APA 500 - Ojo nla l’ ojo ti mo yan

Yoruba Hymn  APA 500 - Ojo nla l’ ojo ti mo yan

APA 500

 1. Ojo nla l’ ojo ti mo yan

 Olugbala l’ Olorun mi:

 O ye ki okan mi ma yo,

 K’o sir o ihin na ka ‘le.

 Ojo nla l’ ojo na!

 Ti Jesu we ese mi nu;

 O ko mi ki mma gbadura,

 Kim ma sora, ki nsi ma yo. 

 Ojo nla l’ ojo na!

 Ti Jesu we ese mi nu.


2. Ise Igbala pari na,

 Mo di t’ Oluwa mi loni;

 On l’o pe mi ti mo si je,

 Mo f’ ayo jipe mimo na.

 Ojo nla, &c.

 

3. Eje mimo yi ni mo je

 F’ Eniti’ o ye lati feran;

 Je k’orin didun kun ‘le Re,

 Nigba mo ba nlo sin nibe.

 Ojo nla, &c.


4. Simi, aiduro okan mi,

 Simi le Jesu Oluwa;

 Tani je wipe aiye dun

 Ju odo awon Angeli?

 Ojo nla, &c

 

5. Enyin orun, gbo eje mi;

 Eje mi ni ojojumo

 Em’ o ma so dotun titi

 Iku y’o fi mu mi re ‘le.

 Ojo nla, &c. Amin.Yoruba Hymn  APA 500 - Ojo nla l’ ojo ti mo yan

This is Yoruba Anglican hymns, APA 500-  Ojo nla l’ ojo ti mo yan . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post