Yoruba Hymn APA 509 - O s’ ohun t’o ti mi loju

Yoruba Hymn APA 509 - O s’ ohun t’o ti mi loju

Yoruba Hymn  APA 509 - O s’ ohun t’o ti mi loju

APA 509

 1. O s’ ohun t’o ti mi loju,

 Pe, nigba kan l’aiye mi,

 Olugbala nkanu lasan,

 O npe mi, mo si ndahun pe,

 “T’ emi sa, nko nani Re.”


2. Sugbon O ri mi; mo si wo

 L’ or igi agbelebu;

 Mo si gbo, “Fiji won Baba,”

 Okan mi f’ inira wipe,

 Em’ o nani Re die.”


3. Lojojumo li anu Re

 Nse ’wosan fun okan mi,

 Agbara at’ ife l’ O fi

 Nfa mi mora, mo si wipe,

 “Ngo nani Re die si.”


4. Ife Re ga ju orun lo,

 O si jin ju okun lo;

 Ife Re na l’ o segun mi,

 Je kin le wi nitoto pe,

 “Em’ o wa fun O titi.” Amin.Yoruba Hymn  APA 509 - O s’ ohun t’o ti mi loju

This is Yoruba Anglican hymns, APA 509- O s’ ohun t’o ti mi loju . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post