Yoruba Hymn APA 512 - Ona Re, Oluwa

Yoruba Hymn APA 512 - Ona Re, Oluwa

Yoruba Hymn  APA 512 - Ona Re, Oluwa

APA 512

 1. Ona Re, Oluwa,

 B’o ti wu k’o di to,

 Fi owo Re to mi,

 Yan ipa mi fun mi.


2. B’o rorun, b’o soro,

 Daradara l’o je;

 B’o run tab’ o wo ni,

 Dandan s’isimi ni.


3. Nko gbodo yan ’pin mi,

 Nko tile je yan a;

 Yan fun mi, Olorun,

 Benin go rin dede.


4. Ijoba t’emi nwa,

 Tire ni; je k’ona

 T’o re ’be je Tire;

 Bi beko ngo sina.


5. Gba, ago mi, fayo

 Tab’ ibanuje kun;

 B’o ti to l’oju Re,

 Yan ’re tab’ ibi mi.


6. Yan ore mi fun mi,

 Aisan tab’ ilera;

 Yan aniyan fun mi,

 Aini tabi oro.


7. Yiyan k’ ise t’emi,

 Ninu ohunkohun;

 Iwo s’oluto mi,

 Ogbon on gbogbo mi. Amin.Yoruba Hymn  APA 512 - Ona Re, Oluwa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 512- Ona Re, Oluwa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post