Yoruba Hymn APA 513 - Gb’ ohun t’o t’ orun wa ti wi

Yoruba Hymn APA 513 - Gb’ ohun t’o t’ orun wa ti wi

Yoruba Hymn  APA 513 - Gb’ ohun t’o t’ orun wa ti wi

APA 513

 1. Gb’ ohun t’o t’ orun wa ti wi,

 F’ awon oku mimo:

 Didun n’ irant’ oruko won,

 ’Busun won n’itura.

2. Nwon ku n’nu Jesu abukun,

 Orun won ti dun to!

 Ninu irora on ese,

 Nwon yo ninu ’danwo.

3. Lona jijin s’aiye ise,

 Nwon mbe lod’ Oluwa;

 Ise won l’aiye iku yi,

 Pari li ere nla. Amin.

Yoruba Hymn  APA 513 - Gb’ ohun t’o t’ orun wa ti wi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 513- Gb’ ohun t’o t’ orun wa ti wi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post