Yoruba Hymn APA 515 - A! nwon ti gun s’ ebute

Yoruba Hymn APA 515 - A! nwon ti gun s’ ebute

Yoruba Hymn  APA 515 - A! nwon ti gun s’ ebute

APA 515

 1. A! nwon ti gun s’ ebute,

 Loke orun; Loke orun;

 Ebi ko ni pa won mo,

 Nwon bo lowo irora,

 Loke orun; Loke orun.


2. A! nwon ko wa fitila,

 Loke orun; Loke orun;

 ’Mole ni l’ojo gbogbo,

 Jesu si n’ Imole won,

 Loke orun; Loke orun.


3. A! wura n’ ita won je,

 Loke orun; Loke orun;

 Ogo ’be sip o pupo,

 Agbo Jesu ni nwon je

 Loke orun; Loke orun.


4. A! otutu ki mu won,

 Loke orun; Loke orun;

 Owore won ti koja,

 Gbogbo ojo l’ o dara;

 Loke orun; Loke orun.


5. A! nwon dekun ija’ ja,

 Loke orun; Loke orun;

 Jesu l’o ti gba won la,

 T’ awon Tire l’ o si nrin,

 Loke orun; Loke orun.


6. A! nwon ko ni sokun mo,

 Loke orun; Loke orun,

 Jesu sa wa lodo won,

 Lodo Re ni ayo wa,

 Loke orun; Loke orun.


7. A! a o dapo mo won,

 Loke orun; Loke orun,

 A nreti akoko wa,

 ’Gba Oluwa ba pe ni

 S’ oke orun; S’ oke orun. Amin.



Yoruba Hymn  APA 515 - A! nwon ti gun s’ ebute

This is Yoruba Anglican hymns, APA 515- A! nwon ti gun s’ ebute. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post