Yoruba Hymn APA 536 - Jesu, nib’ eni Re pade

Yoruba Hymn APA 536 - Jesu, nib’ eni Re pade

Yoruba Hymn  APA 536 - Jesu, nib’ eni Re pade

APA 536

 1. Jesu, nib’ eni Re pade

 Nibe, nwon r’ ite anu Re;

 Nibe, nwon wa O, nwon ri O,

 Ibikibiki n’ ile owo.


2. Ko s’ ogiri t’o se O mo,

 O ngbe inu onirele;

 Nwon nmu O wa bi nwon ba wa,

 ‘Gba nwon nlo ‘le, nwon mu O lo.


3. Olusagutan eni Re,

 So anu Re ‘gbani d’otun;

 So adun oruko nla Re

 Fun okan ti nwa oju Re.


4. Je k’a r’ipa adua nihin,

 Lati so ‘gbagbo di lile,

 Lati gbe ife wa soke,

 Lati gb’ orunka ‘waju wa.


5. Oluwa, ‘Wo wa nitosi,

 N’ apa Re, de ‘ti Re sile;

 Si orun, sokale kankan,

 Se gbogbo okan ni Tire. Amin.Yoruba Hymn  APA 536 - Jesu, nib’ eni Re pade

This is Yoruba Anglican hymns, APA 536-  Jesu, nib’ eni Re pade. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post