Yoruba Hymn APA 540 - Gb’ okan mi gege b’o ti ri

Yoruba Hymn APA 540 - Gb’ okan mi gege b’o ti ri

Yoruba Hymn  APA 540 - Gb’ okan mi gege b’o ti ri

APA 540

 1. Gb’ okan mi gege b’o ti ri,

 Te ite Re sibe;

 Ki nle fe O ju aiye lo,

 Ki mwa fun O nikan.


2. Pari ‘se Re Oluwa mi,

 Mu mi je oloto;

 K’ emi le gbohun Re, Jesu,

 Ti o kun fun ife.


3. Ohun ti nko mi n’ ife Re,

 Ti nso ‘hun ti mba se;

 Ti ndoju ti mi, nigba nko

 Ba topa ona Re.


4. Em’ iba ma ni eko yi,

 T’ o nti odo Re wa;

 Ki nko ‘teriba s’ ohun Re,

 At’ oro isoye. Amin.Yoruba Hymn  APA 540 - Gb’ okan mi gege b’o ti ri

This is Yoruba Anglican hymns, APA 540-  Gb’ okan mi gege b’o ti ri. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post