Yoruba Hymn APA 539 - Mura ebe, okan mi

Yoruba Hymn APA 539 - Mura ebe, okan mi

 Yoruba Hymn  APA 539 - Mura ebe, okan mi

APA 539

1. Mura ebe, okan mi,

 Jesu nfe gb’ adura re;

 O ti pe k’ o gbadura,

 Nitorina yio gbo.


2. Lodo Oba n’ iwo mbo,

 Wa lopolopo ebe;

 Be l’ ore-ofe Re po,

 Ko s’ eni ti bere ju.


3. Mo t’ ibi eru bere;

 Gba mi ni eru ese!

 Ki eje t’O ta sile,

 We ebi okan mi nu.


4. Sodo Re mo wa simi,

 Oluwa, gba aiya mi;

 Nibe ni ki O joko,

 Ma je oba okan mi.


5. N’ irin ajo mi l’aiye,

 K’ ife Re ma tu mi n’nu;

 Bi ore at’ oluso,

 Mu mi dopin irin mi.


6. F’ ohun mo ni se han mi,

 Fun mi l’ otun ilera;

 Mu mi wa ninu ’gbagbo,

 Mu mi ku b’ enia Re. Amin.Yoruba Hymn  APA 539 - Mura ebe, okan mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 539-  Mura ebe, okan mi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post