Yoruba Hymn APA 600 - Olorun, d’ Oba si

Yoruba Hymn APA 600 - Olorun, d’ Oba si

Yoruba Hymn  APA 600 - Olorun, d’ Oba si

APA 600

 1. Olorun, d’ Oba si,

 K’Oba k’o pe titi,

 Da Oba si.

 Jo, fun ni isegun,

 Irora at’ ogo,

 K’ o job ape titi,

 Da Oba si.


2. Dide, Olorun wa,

 T’ awon ota re ka,

 Bi won subu.

 Mu idamu ba won,

 Fo ’gba rikisi won,

 Iwo l’ a gbekele,

 Jare gba wa.


3. Fi ebun rere Re

 Te Oba wa lorun,

 K’o pe titi.

 K’o duro ti ofin,

 K’ a le ma f’ ayo wi

 Lati okan wa pe,

 Da Oba si. Amin.Yoruba Hymn  APA 600 - Olorun, d’ Oba si

This is Yoruba Anglican hymns, APA 600- Olorun, d’ Oba si. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post