Yoruba Anglican Hymn Apa 20 - Wo Imole! larin okun aiye

Yoruba Anglican Hymn Apa 20 - Wo Imole! larin okun aiye

Yoruba Hymn Apa 20 - Wo Imole! larin okun aiye

APA 20

 1. ’Wo Imole ! larin okun aiye,

 Ma sin mi lo.

 Okunkun su, mo si jina s’ ile;

 Ma sin mi lo.

 To ’sise mi: ohun ehin ola

 Emi ko bere; ’sise kan to fun mi.

 

2. Nigbakan ri, emi ko be O, pe

 Ma sin mi lo;

 Beni nko fe O; sugbon nigbayi

 Ma sin mi lo.

 Afe aiye ni mo ti nto lehin;

 Sugbon Jesu, ma ranti igbani.

 

3. Ipa Re l’ o ti ndi mi mu, y’ o si

 Ma sin mi lo;

 Ninu ere ati yangi aiye,

 Ma sin mi lo,

 Titi em’ o fi ri awon wonni

 Ti mo fe, tin won ti f’ aiye sile.

 

4. K’ o to d’ igba na, l’ ona aiye yi

 T’ iwo ti rin,

 Ma sin mi lo, Jesu Olugbala

 S’ ile Baba;

 Kin le simi lehin ija aiye

 ninu imole ti ko nipekun. Amin



This is Yoruba Anglican Hymn Apa 20 - Wo Imole ! larin okun aiye. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post