Yoruba Hymn Apa 20 - Wo Imole! larin okun aiye APA 20 1. ’Wo Imole ! larin okun aiye, Ma sin mi lo. Okunkun su, mo si jina s’ ile; Ma sin mi lo. To ’sise mi: ohun ehin ola Emi ko bere; ’sise kan to fun mi. 2. Nigbakan ri,…
Yoruba Hymn Apa 19 - Ero di| dun kan| nso APA 14 1. Ero di| dun kan| nso S’okan | mi fi| rifi| ri- Mo sunmo ’le | mi lo | ni, Ju bi | mo ti | sunmo | ri. 2. Mo sunmo | ’te nla | ni, Mo sunm’ | okun | Krista li, Mo sunmo …
Yoruba Hymn Apa 18 - Baba, a tun pade l’oko Jesu APA 18 1. Baba, a tun pade l’oko Jesu, A si wa teriba lab’ ese Re: A tun fe gb’ ohun wa soke si O Lati wa anu, lati korin ’yin. 2. A yin O fun itoju ’gbagbogbo, Ojojumo l’ a…
Yoruba Hymn Apa 17 - L’ oju ale, ’gbat ’orun wo APA 14 1. L’ oju ale, ’gbat ’orun wo, N won gbe abirun w’ odo Re: Oniruru ni aisan won, Sugbon nwon f’ ayo lo ’le won. 2. Jesu a de l’ oj’ ale yi, A sunmo, t’ awa t’ arun wa, …
Yoruba Hymn Apa 16 - Iwo Imole okan mi APA 14 1. Iwo Imole okan mi, Li odo Re oru ko si, Ki kuku aiye ma bo O, Kuro l’ oju iranse Re. 2. Nigbat’ orun ale didun Ba npa ipenpeju mi de, K’ ero mi je lati simi Lai laiya Olu…
Yoruba Hymn Apa 15 - Wa ba mi gbe! ale fere le tan APA 15 1. Wa ba mi gbe ! ale fere le tan, Okunkun nsu; Oluwa ba mi gbe, Bi oluranlowo miran ba ye, Iranwo alaini, wa ba mi gbe ! 2. Ojo aiye mi nsare lo s’opin, Ayo aiye nku,…
Yoruba Hymn Apa 10 - Baba mi gbo temi APA 10 1. Baba mi gbo temi ! ’Wo ni alabo mi, Ma sunmo mi titi: Oninure julo ! 2. Jesu Oluwa mi, Iye at’ ogo mi, K’ igba na yara de, Ti ngo de odo Re. 3. Olutunu julo, ’Wo ti ngbe in…
Yoruba Hymn APA 3 - Nigbat’ imole owuro APA 3 1. Nigbat’ imole owuro B anti ila orun tan wa, A! Orun ododo mimo Ma sai fi anu ran si mi ! Tu isudede ebi ka S’ okunkun mi d’ imole nla. 2. ’Gbati mba m’ ebo oro wa ’Waju Oloru…
Yoruba Hymn APA 4 - Oluwa mi, mo njade lo APA 4 1. Oluwa mi, mo njade lo, Lati se ise ojo mi; Iwo nikanl’ emi o mo, L’ oro, l’ ero, ati n’ ise. 2. Ise t’ o yan mi, l’ anu Re, Je ki nle se tayotayo; Ki nr’ oju Re ni ise …
Yoruba Hymn Apa 5 - Wa s’odo mi, Oluwa mi APA 5 1. Wa s’odo mi, Oluwa mi, Ni kutukutu owuro; Mu k’ ero rere so jade, Lat’ inu mi soke orun. 2. Wa s’odo mi Oluwa mi, Ni wakati osan gangan; Ki ’yonu ma ba se mi mo Nwon a si s…
Yoruba Hymn Apa 6 - Krist, Ologo, Olola APA 6 1. Krist, Ologo, Olola, Iwo imole aiye, Orun ododo, dide, K’ o si bori okunkun; ‘Mole oro, sunmo mi, ‘Rawo oro, w’aiya mi. 2. Okunkun l’owuro je B’ Iwo ko pelu re wa; Ailayo l’ojo yi …
Yoruba Hymn APA 100 - Alakoso ti orun APA 100 1. Alakoso ti orun, Alanu at’ Ologbon; Igba mi mbe lowo Re, Opin gbogbo l’ase Re. 2. Ase Re l’o da aiye Ati ibi mi pelu; Obi, ile, on igba; Nipa Re ni gbogbo won. 3. Igb’ ais…
Yoruba Hymn APA 80 - Wo ! gbogbo ile okunkun APA 80 1. Wo ! gbogbo ile okunkun, Wo ! okan mi, dro je; Gbogbo ileri ni o nso T’ ojo ayo t’o l’ogo; Ojo ayo ! Ojo ayo ! K’ owuro re yara de ! 2. Ki India on Afrika, K’ alaigbed…
Yoruba Hymn APA 79 - Ojo ayo nlanla na de APA 79 1. Ojo ayo nlanla na de, Eyi t’ araiye ti nreti; Nigbat’ Olugbala w’ aiye Nigbat’ a bi ninu ara. 2. Olusagutan ni papa Bi nwon tin so agutan won, Ni ihin ayo na ko ba. Ihin …
Yoruba Hymn APA 78- Onigbagbo, e bu s’ ayo APA 78 1. Onigbagbo, e bu s’ ayo, Ojo nla l’ eyi fun wa; E gbo bi awon Angeli Ti nf’ ogo fun Olorun: Alafia, Alafia Ni fun gbogbo enia . 2. Ki gbogbo aiye ho f’ ayo, K’ a f’ ogo…
Yoruba Hymn APA 77- Eyin Angel l’ orun ogo APA 77 1. Eyin Angel l’ orun ogo, To yi gbogbo aiye ka; E ti korin dida aiye, E so t’ ibi Messia; E wa josin, E wa josin, Fun Kristi Oba titun. 2. Enyin Oluso-agutan, Ti nso er…
Yoruba Hymn APA 76 - E ji enyin enia APA 76 1. E ji enyin enia E ma se sun titi; A ! Imole wa nlanla On li o yo de yi. Orun n’ imole ara, Jesu ni ti okan ? Ireti awon baba Yio ha de lasan ? 2. O de k’ ewon ese tu O de …
Yoruba Hymn APA 75- Ji, ’wo Kristian, k’ o ki oro ayo APA 75 1. Ji, ’wo Kristian, k’ o ki oro ayo Ti a bi Olugbala araiye; Dide, k’ o korin ife Olorun, T’ awon Angeli nko n’ ijo kini. Lat’ odo won n’ ihin na ti bere; Ihin …
Yoruba Hymn APA 73- Ojo dajo, ojo eru APA 73 1. Ojo dajo, ojo eru! Gbo bi ipe tin dun to! O ju egbarun ara lo, O sin mi gbogbo aiye. Bi esun na Y’o ti damu elese! 2. Wo Onidajo l’awo wa, T‘o woo go nla l’aso Gbogbo won ti…
Yoruba Hymn APA 74- Gbe ori nyin s’ oke, enyin APA 74 1. Gbe ori nyin s’ oke, enyin ’Lekun aiyeraiye: Gba Oba ogo: wo, o mbo Pel’ ogun orun re. Ta l’ Oba Ogo yi ? Tani ? Oluwa t’ o n’ ipa T’ o l’ agbara l’or’ ota Re, Ase…