Yoruba Hymn APA 46 - Olorun ’fe, Isun anu

Yoruba Hymn APA 46 - Olorun ’fe, Isun anu

Yoruba Hymn APA 46 -  Olorun ’fe, Isun anu

APA 46

 1. Olorun ’fe, Isun anu,

 Ore Re tip o to !

 Orisi akoko t’ o nde

 L’ o nkede ajo Re.


2. Nigbat’ agbe gbin ogbin re,

 T’o ri mo ’nu ile,

 Iwo m’ akoko ti o nhu,

 O si ran ojo wa.


3. Tire l’ agbara t’ ojo ni,

 T’o nmu ’rugbin dagba;

 ’Wo l’o nran ’mole orun wa,

 Ati iri pelu.


4. Akoko ’rugbin on ’kore,

 Iwo l’o fi fun wa;

 Ma je k’ a gbagbe lati mo

 Ibi ’bukun ti nwa.

 

5. Isun ife, ’Wo n’ iyin wa;

 Iwo l’a nkorin si,

 Gbogbo eda l’ o si dalu

 N’nu iyin didun na. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 46 - Olorun ’fe, Isun anu. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post