Yoruba Hymn APA 47 - Ojo ibukun y’o siro

Yoruba Hymn APA 47 - Ojo ibukun y’o siro

 Yoruba Hymn  APA 47 - Ojo ibukun y’o siro

APA 47

 1. Ojo ibukun y’o siro!

 Ileri ife l’eyi;

 A o ni itura didun

 Lat’odo Olugbala.

 Ojo ibukun ! Ojo ibukun l’a nfe;

 Iri anu nse yi wa ka, sugbon ojo l’a ntoro.


2. Ojo ibukun y’o siro !

 Isoji iyebiye;

 Lori oke on petele

 Iro opo ojo mbo

 Ojo ibukun, &c.


3. Ojo ibukun y’o siro

 Ran won si wa Oluwa !

 Fun wa ni itura didun

 Wa, f’ ola fun oro Re.

 Ojo ibukun, &c.

 

4. Ojo ibukun y’o siro

 Iba je le ro loni !

 B’ a ti njewo f’ Olorun wa

 T’a npe oruko Jesu.

 Ojo ibukun ! Ojo ibukun l’a nfe;

 Iri anu nse yi wa ka, sugbon ojo l’a ntoro. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 47 - Ojo ibukun y’o siro. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post