Yoruba Hymn APA 50 - Ojo ’dajo on ’binu

Yoruba Hymn APA 50 - Ojo ’dajo on ’binu

Yoruba Hymn APA  50- Ojo ’dajo on ’binu

APA 50

1. Ojo ’dajo on ’binu,

 Ojo ti Jesu pa ni,

 Gongo a so n’ ijo na !


2. Kikan n’ ipe o ma dun,

 Isa oku yio si,

 Gbogbo oku y’o dide.


3. Iku papa y’o diji,

 Eda gbogbo y’o dide

 Lati j’ ipe Olorun.


4. A o si Iwe sile,

 A o si ka ninu re

 Fun ’dajo t’oku t’aye.

 

5. Onidajo Ododo,

 Jo w’ ese mi gbogbo nu

 K’ ojo ’siro na to de. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 50 - Ojo ’dajo on ’binu. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم