Yoruba Hymn APA 53 - Oluwa agbara fohun

Yoruba Hymn APA 53 - Oluwa agbara fohun

Yoruba Hymn  APA 53- Oluwa agbara fohun

APA 53

 1. Oluwa agbara fohun,

 Bi ara l’oke Sinai;

 Awon Israeli gbohun Re,

 Nwon sig bon fun iberu:

 Okunkun su biribiri;

 Ati l’otun ati l’osi,

 Awon apata nfaya.


2. Oluwa ife je ’rora

 L’ori oke Kalfari:

 O gbe oju soke orun,

 L’akoko wahala Re:

 Fun wa l’o ru eru egbe,

 Fun wa l’o t’ eje Re sile,

 T’o sit u Baba l’oju.

 

3. Oba ife at’ agbara,

 Oluwa eda gbogbo,

 O npada bo ninu ogo,

 Lati wa gba ijoba;

 Ipe y’o dun, angel y’o ho,

 Halleluya y’o j’orin won

 L’ori Esu at’ iku. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 53 - Oluwa agbara fohun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post