Yoruba Hymn APA 61 - Ara mi fun’ rugbin rere

Yoruba Hymn  APA 61 - Ara mi fun’ rugbin rere

APA 61

1. Ara mi fun’ rugbin rere,

 Nigba ifunrugbin wa,

 Ma sise l’ oruko Jesu,

 Tit’ On o tun pada wa,

 Nigbana ni a o f’ ayo ka a,

 Olukore a ko won si aba.


2. Olugbala pase wipe,

 “Sise nigbat’ o j’ osan;”

 Oru mbowa,” mura giri,

 Oloko fere de na

 Nigbana ni, &c.


3. T’ agba t’ ewe jumo ke, pe,

 ’Wo l’ oluranlowo wa;

 Mu ni funrugbin igbagbo,

 K’ a s’ eso itewogba.

 Nigbana ni, &c.


4. Lala ise fere d’ opin,

 Owo wa fe ba ere;

 B’ o de ninu Olanla Re,

 Y’o so fun wa pe, “Siwo.”

 Nigbana ni a o f’ ayo ka a,

 Olukore a ko won si aba. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 61 - Ara mi fun’ rugbin rere. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post