Yoruba Anglican Hymn APA 63 - L’ eba odo Jordani ni

Yoruba Anglican Hymn APA 63 - L’ eba odo Jordani ni

Yoruba Hymn APA 63 - L’ eba odo Jordani ni

APA 63

1. L’ eba odo Jordani ni,

 Onibaptisi nke wipe;

 Oluwa mbo ! Oluwa mbo !

 E gbo ’hin ayo; Oba mbo.


2. K’ese tan ni gbogbo okan,

 K’ Olorun ba le ba wa gbe;

 K’ a pa ile okan wa mo

 Ki Alejo nla yi to de.


3. Jesu, iwo n’ igbala wa,

 Esan, ati alabo wa;

 B’ itanna l’ awa ’ba segbe

 Bikose t’ ore-ofe Re.


4. S’ awotan awon alaisan,

 Gb’ elese t’ o subu dide;

 Tan’mole Re ka ’bi gbogbo,

 Mu ewa aiye bo s’ ipo.

 

5. K’ a f’ iyin f’ Omo Olorun,

 Bibo eni ’mu dande wa;

 Eni t’ a nsin pelu Baba,

 At’ Olorun Emi Mimo. Amin.This is Yoruba Anglican hymns, APA 63 - Mo ji, mo ji, ogun orun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post