Yoruba Hymn APA 64 - Iwo Onidajo

Yoruba Hymn APA 64 - Iwo Onidajo

Yoruba Hymn  APA 64 - Iwo Onidajo

APA 64

1. Iwo Onidajo,

 A fere duro na,

 Pelu ayo tabi eru,

 Niwaju ite Re:

 Jo pese okan wa,

 Fun ojo nlanla ni;

 Fi emi irora kun wa

 At’ emi adura.


2. K’ a ma wo ona Re,

 L’ akoko aimo ni;

 Nigbat’ Iwo o sokale,

 Ninu Olanla Re.

 Iwo eni aiku

 Lati da wa lejo;

 T’ iwo ti ogun Baba Re

 At’ ore-ofe Re.


3. K’ a le ba wa bayi

 Nigboran s’ oro Re;

 K’ a ma teti s’ohun ipe,

 K’ a ma wo ona Re.

 K’ a wa ipo ayo

 T’ awon olubukun,

 K’ a si sora nigba die,

 Fun ’simi ailopin. Amin.

Yoruba Hymn  APA 64 - Iwo Onidajo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 64 - Iwo Onidajo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post