Yoruba Hymn APA 69 - Enyin t’ o ngb’ oke orun

Yoruba Hymn APA 69 - Enyin t’ o ngb’ oke orun

Yoruba Hymn  APA 69- Enyin t’ o ngb’ oke orun

APA 69

 1. Enyin t’ o ngb’ oke orun,

 E so ‘Ta l’ Oba Ogo’ ?

 Ta l’ o ga julo nibe ?

 T’ o si l’ agbara gbogbo?


2. Od’ Agutan nikan ni,

 L’ o pe oye na ni t’ On;

 On l’ o wa lori ite,

 On si ni Oba Ogo.


3. Ihin nla ! Jesu l’ Oba,

 On nikan l’ o si joba;

 W’ odo Re t’ enyin t’ ore,

 E’ wole niwaju Re.


4. Je k’ aiye k’ o rerin Re,

 Je kin won ko lati sin,

 Angle nyo l’ oruko Re,

 Gbogbo eda orun nsin.

 

5. A yin O, ’Wo t’ Angel nsin,

 Od’ Agutan Olorun,

 Ma joba titi lailai

 Oba ye O, Oluwa. Amin.

Yoruba Hymn  APA 69- Enyin t’ o ngb’ oke orun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 69 - Enyin t’ o ngb’ oke orun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post