Yoruba Hymn APA 2 - Mo ji, mo ji, ogun orun

Yoruba Hymn APA 2 - Mo ji, mo ji, ogun orun

 Yoruba Hymn APA 2 - Mo ji, mo ji, ogun orun

APA 2

1. Mo ji, mo ji, ogun orun,

 K’ emi l’ agbara bi tin yin;

 K’ emi ba le lo ojo mi

 Fun iyin Olugbala mi.

 

2. Ogo fun Enit’ o so mi,

 T’o tu mi lara loj’ orun;

 Oluwa ijo mo ba ku,

 Ji mi s’ aiye ainipekun.

 

3. Oluwa mo tun eje je,

 Tu ese ka b’ iri oro;

 So akoronu mi oni,

 Si f’ Emi Re kun inu mi.

 

4. Oro at’ ise mi oni

 Ki nwon le ri bi eko Re;

 K’ emi si f’ ipa mi gbogbo

 Sise rere fun Ogo Re. Amin.


This is Yoruba Anglican hymns, APA 2 - Mo ji, mo ji, ogun orun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post