Yoruba Hymn APA 120 - Oluwa y’o tip e to

Yoruba Hymn APA 120 - Oluwa y’o tip e to

Yoruba Hymn  APA 120 - Oluwa y’o tip e to

APA 120

 1. Oluwa y’o tip e to

 Ti ’Wo o tun pada

 Are fere mu wa tan,

 Bi a ti nwona Re;

 Oluwa, y’o ti pe to

 Ta o ma reti Re ?

 Opo ni ko gbagbo mo

 P ’Wo o tun pada.


2. Oluwa y’o tip e to

 Ti ’Wo o kesi wa ?

 Ti awa, ti nreti Re

 Yio ri O l’ ayo ?

 Ji, wundia ti o sun,

 Lo kede bibo Re

 Ki gbogbo awon t’ o sun

 Le mo pe O mbo wa.


3. Dide, tan fitila re,

 Gbe ewu mimo wo,

 Mura lati pade Re,

 ’Tori On fere de.

 Oluwa, y’o tip e to

 Ti ’Wo o tun pada ?

 Ma je ki are mu wa

 Tit’ a o fi ri O. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 120-  Oluwa y’o tip e to . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post