Yoruba Hymn APA 122 - Elese, wa sodo Jesu

Yoruba Hymn APA 122 - Elese, wa sodo Jesu

Yoruba Hymn  APA 122 - Elese, wa sodo Jesu

APA 122

 1. Elese, wa sodo Jesu

 Eni t’ o wa gba o la;

 Eni t’ o gbe ara re wo

 Lati ru irora re.


2. Olodumare ni Eni

 T’ o fie mi Re fun o;

 Orun at’ aiye y’o koja

 Sugbon On wa titi lai.


3. Ki ojo aiye re to pin,

 K’ iku to p’ oju re de,

 Yara, wa Olugbala re,

 K’ akoko na to koja.


4. Gbo b’ ohun Re ti nkepe o,

 “ Elese wa sodo Mi

 Ko eru re na to Mi wa;

 Gbagbo, reti, ma beru.” Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 122 -  Elese, wa sodo Jesu . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post