Yoruba Hymn APA 132 - Lo wasu ihinrere mi

Yoruba Hymn APA 132 - Lo wasu ihinrere mi

 Yoruba Hymn  APA 132 - Lo wasu ihinrere mi

APA 132

1. Lo wasu ihinrere mi,

 Mu gbogbo aiye gb’ ore mi;

 Enit’ o gb’ oro mi y’o la,

 Enit’ o ko yio segbe.


2. Emi o f’ oye nla han nyin,

 E o f’ oro oto mi han;

 Ni gbogbo ise ti mo se,

 Ni gbogbo ise t’ e o se.


3. Lo wo arun, lo j’oku nde,

 F’ oruko mi l’ Esu jade;

 Ki woli mi mase beru,

 Bi Griki ati Ju kegan.


4. Ko gbogbo aiye l’ ase mi,

 Mo wa lehin nyin de opin;

 Lowo mi ni gbogbo ipa,

 Mo le pa, mo si le gbala.


5. Imole si ran yi i ka,

 Ogo nla l’ o fi lo s’ orun;

 Nwon si mu deile jijin,

 Ihin igoke Olorun. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 132 - Ma sise lo, mase sare . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post