Yoruba Hymn APA 131 - Iwo ti okunkun

Yoruba Hymn APA 131 - Iwo ti okunkun

Yoruba Hymn  APA 131 - Iwo ti okunkun

APA 131

 1. Iwo ti okunkun

 Gb’ oro agbara Re,

 T’o si fo lo:

 Gbo ti wa, a mbe O,

 Nibit’ Ihinrere

 Ko ti tan mole re,

 K’ imole wa.


2. ‘Wo t’ iye apa Re

 Mu iriran w’a iye,

 At’ ilera:

 Ilera ti inu:

 Iriran ti okan;

 Fun gbogbo enia,

 K’ imole wa.


3. Iwo Emi oto,

 Ti o nf’ iye fun wa,

 Fo kakiri:

 Gbe fitila anu,

 Fo ka oju mi,

 Nibi okunkun nla,

 K’ imole wa.

 

4. Metalokan Mimo,

 Ogbon, Ife, Ipa,

 Alabukun!

 B’ igbi omi okun

 Ti nyi ni ipa re,

 Be ka gbogbo aiye,

 K’ imole wa. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 131 - Iwo ti okunkun . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post