Yoruba Hymn APA 171 - Bi agborin tin mi hele

Yoruba Hymn APA 171 - Bi agborin tin mi hele

Yoruba Hymn  APA 171 - Bi agborin tin mi hele

APA 171

 1. Bi agborin tin mi hele,

 S’ ipa odo omi;

 Beni okan mi nmi si O,

 Iwo Olorun mi.


2. Orungbe Re ngbe okan mi,

 Olorun alaye;

 Nigbawo ni ngo r’oju mi,

 Olorun Olanla ?


3. Okan mi, o se rewesi ?

 Gbekele Olorun;

 Eniti y’o so ekun re

 D’orin ayo fun o.


4. Y’o tip e to, Olorun mi,

 Ti ngo d’eni ’gbagbe ?

 Tao ma ti mi sihin sohun,

 B’eni ko ni ’bugbe ?


5. Okan mi, o se rewesi ?

 Gbagbo, ’wo o si ko

 Orin iyin s’ Olorun re,

 Orisun emi re. Amin.

Yoruba Hymn  APA 171 - Bi agborin tin mi hele

This is Yoruba Anglican hymns, APA 171-  Bi agborin tin mi hele. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post