Yoruba Hymn APA 172 - Bi mo ti ri laisawawi

Yoruba Hymn APA 172 - Bi mo ti ri laisawawi

 Yoruba Hymn  APA 172 - Bi mo ti ri laisawawi

APA 172

1. Bi mo ti ri laisawawi,

 Sugbon nitori eje Re;

 B’o si ti pe mi pe ki mwa

 Olugbala, mo de.


2. Bi mo ti ri laiduro pe,

 Mo fe k’okan mi mo toto,

 S’odo Re t’o le we mi mo,

 Olugbala, mo de.


3. Bi mo ti ri b’o tile je

 Ija l’ode, ija ninu,

 Eru l’ode eru ninu,

 Olugbala, mo de.


4. Bi mo ti ri osi, are,

 Mo si nwa imularada;

 Iwo l’o le s’awotan mi,

 Olugbala, mo de.


5. Bi mo ti ri ’Wo o gba mi,

 Wo o gba mi t’owo t’ese;

 ’Tori mo gba ’leri Re gbo,

 Olugbala, mo de.


6. Bi mo ti ri ife Tire,

 L’o sete mi patapata;

 Mo di tire, tire nikan,

 Olugbala, mo de. Amin.

 Yoruba Hymn  APA 172 - Bi mo ti ri laisawawi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 172-  Bi mo ti ri laisawawi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post