Yoruba Hymn APA 190 - Ibu anu ! O le je

Yoruba Hymn APA 190 - Ibu anu ! O le je

Yoruba Hymn  APA 190 - Ibu anu ! O le je

APA 190

 1. Ibu anu ! O le je

 Pe anu si mbe fun mi ?

 Olorun le mu suru

 F’ em’ olori elese ?

 Mo ti ko or-ofe Re,

 Mo bi n’nu lojukoju;

 Nko f’ eti si ipe Re;

 Mo so ninu l’ ainiye.


2. Mo tan a ni suru to:

 Sibe o si da mi si;

 O nke, “Ngo se jowo re !

 Sa gba ago igbala.

 Olugbala mi nduro,

 O si nfi ogbe Re han;

 Mo mo, ife l’ Olorun;

 Jesu nsun, O feran mi.


3. Jesu, dahun lat’ oke;

 Ife k’ iwa Re gbogbo ?

 ’Wo ki y’o dariji mi,

 Ki nwole lie se Re ?

 Bi ’m’ ba mo inu Re ‘re,

 B’ Iwo ’ba se alanu,

 F’ anu deti Re sile,

 Dariji, k’o si gba mi.


4. F’ oju iyonu wo mi;

 Fi wiwo oju pe mi;

 Mu okan okuta ro;

 Yipada, ro mi lokan.

 Mu mi ronupiwada;

 Je ki ngbawe f’ ese mi;

 Ki nsi kanu ise mi,

 Ki ngbagbo, kin ye dese. Amin.

Yoruba Hymn  APA 190 - Ibu anu ! O le je

This is Yoruba Anglican hymns, APA 190 -  Ibu anu ! O le je  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post