Yoruba Hymn APA 192 - Iwo elese, Emi nfi anu pe

Yoruba Hymn APA 192 - Iwo elese, Emi nfi anu pe

 Yoruba Hymn  APA 192 - Iwo elese, Emi nfi anu pe

APA 192

1. Iwo elese, Emi nfi anu pe

 Okan re t’o ti yigbi ninu ese;

 Mase ba Emi ja, ma pe titi mo,

 Ebe Olorun re le pari loni.


2. Omo Ijoba, ma s’m eru ese mo;

 Gb’ ebun Emi Mimo ati itunu:

 Ma bi Emi ninu, Oluko re ni, -

 K’a ba le se Olugbala re logo.


3. Tempili d’ ibaje, ewa re d’ ile;

 Ina pepe Olorun fere ku tan,

 Bi a fi ife da, O si le tun ran :

 Mase pa’na Emi, Oluwa mbo wa. Amin.

 Yoruba Hymn  APA 192 - Iwo elese, Emi nfi anu pe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 192 -  Iwo elese, Emi nfi anu pe . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post